close
Jump to content

Ambruse Vanzekin

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Ambruse Vanzekin
Personal information
OrúkọAmbrose Vanzekin
Ọjọ́ ìbí14 Oṣù Keje 1986 (1986-07-14) (ọmọ ọdún 40)
Ibi ọjọ́ibíNigeria
Ìga1.76 m (5 ft 9 in)
Playing positionGoalkeeper
Club information
Current clubWarri Wolves F.C.
Number1
Plateau United
Senior career*
YearsTeamApps(Gls)
2004-2006Plateau United
2006-2008Bendel Insurance F.C.23(0)
2008-2009Akwa United F.C.
2009-Warri Wolves F.C.
National team
2003Nigeria U-173(0)
2005Nigeria U-207(0)
2008Nigeria U-236(0)
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only.
† Appearances (Goals).

Ambruse Vanzekin (ojoibi 14 July 1986) je amúlé/gooli ọmọ orílẹ̀ èdè Naijiria tí ón gbá boolu lowolowo fún ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù Warri Wolves F.C..


Iṣẹ́ Ìṣe Gégébí Agbábóólù

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Vanzekin bèrè Gẹ́gẹ́ bí agbábọ́ọ̀lù nínú ikò Plateau United kí wọ́n tó gbé lọ sínú ikò agbábóòlù Bendel Insurance F.C. ní ọdún 2006. Ó kúrò ní Egbe agbábóòlù Insurance nínú Oṣu ìkínni ọdún 2008 lọ sí inú ikò Akwa United F.C. kí wọ́n tó fìdí remi nínú ṣáá ọdún 2008–09. Vanzekin kúrò nínú ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù Akwa United F.C. nínú Oṣù keje ọdún 2009 lọ sí inú ikò agbábóòlù Warri Wolves.[1]

Iṣẹ́ Ìṣe Gégébí Agbábóólù Ní Àgbáyé

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ó wà lára àwọn ikò ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù òjè-wẹ́wẹ́ orile-ede Naijiria ti wọn gba àmì ẹyẹ fádákà nínú ìdíje tí 2008 Summer Olympics tí ó sì tún jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù òjè-wẹ́wẹ́ tí wọ́n kópa nínú ìdíje 2003 FIFA U-17 World Championship àti U-20[2] níbi ìdíje 2005 FIFA World Youth Championship, níbi tí wọ́n ti gbé ipò keji,[3] látàrí bí Argentina ṣe na won ni àmì ayọ̀ méjì sí eyokan (1–2) ní bi asekagba ìdíje ifesewonse na.[4]

Àwọn Àmì Ìdánilólá

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]